音效
界面
难度等级
口音
界面语言
1
和/或在社交方面支持我。网络:
Beast & Peace
(专辑: Blessed - 2023)
(The winds will come) (To steal the
words I
say) Imole Ahn Ahn, mó silent mood, but beast ní mí Mo lé cause violence but still, peace ní mí You don't have to hurt me, before you win You don't have to kill somebody before you sin Óṣá lé browse, láì dè ló sub oh Òde lé go far without God oh So, mó dúró t'Olùwà So, kò kín ṣe irú wá Even tọbà fún yín làbọ pẹ'lú spoon, ẹ lè j'ojú wá Èmi má dẹ tí bad, láti àyé la'dì-la'dì Láti àyé 1990 tó ńlù beat pati-pati Èmi tímo feel bad, mó dẹ tí feel good Now, mó feel better, Surulere bí Ojuelegba Torípé mó wọ ńkán, wọn sọ pé mowà on drug Now, mowà on top, life mí òdẹ ní contour Mó pàwọn ni Naija, ó tún báwọn ní London Fún wọn ní KPK, Ponmo, Light boy wo, mo ńta'na (Light-boy mo ńta'na) Uh, mummy mí àti daddy mí, wọn kàn ló ń question mí Wọn ní, "Ìbò l'otí rí vibe yi, ṣé ọwọ demon?" Àwọn tọ senior mí, wọn bèrè, "Where you see money?" Àwọn tí mó jùlọ, wọn photocopy mí First cashout mí, ọmọ ìyá, mó dè fí rá bazooka Mo kó fún àwọn sharp shooter Ẹ má bínú tọbá dá sí'ta Tra-ta-ta-ta-ta-ta fún àwọn fake nigga Àwọn t'ofẹ shame mí Wo, èmi wá shameless Wọn fẹ stain white mí, but mo wá stainless Àwọn nigga tọ leave mí, wọn lé rí realness Torí pé silence mí, no mean say na weakness Shoutout sí Iba J, Diarra, pẹ'lú Hayan CY, Darosha, Prime Boy Spending with my daddy, life mí wá splendid Ológo, Zomo, TIA, Bella (Chukwuchilly) Soul Mí ṣámọ Wọn ní irú ẹ Irú ẹ tóní, kò kíń ṣe original (Boombah) O
fẹ, o
fẹ sùn mó mí But, kò kíń ṣe òun gan-gan
完毕