Se Bo'timo
(专辑: Merchants, Dealers & Slaves - 2013)
Ijapa o
n'ibi ti o n
lo Kele kele, o n
rin, o n
lo Araye n
yimu, o n
lo Ero wa, ero lo, o n
lo Ko gba agidi O
ro bi A, B, D
Ti o
ba koju mo tie Ti mo koju mo temi Bi a
ba fi eyin si owo otun Ki a
feyin sowo osi Ki awa f'eyin rin lati ahin titi de iseyin Eni ma yini, a
yini Eni o
ni yini, ko ni yini Se bo'timo ore Se bo'timo ore mi Se bo'timo mama Se bo'timo baba mi Won n
tan e
Dakun ye maa tan ara re T'ire n
t'ire Ye ma ko ara re Bi o
ba sare, bo subu Iwo lo lara re B'ole, b'oro Ore, ma paara ire Ko gba agidi O
ro bi A, B, D
Ti o
ba koju mo tie Ti mo koju mo temi Bi a
ba fi eyin si owo otun Ki a
feyin sowo osi Ki awa f'eyin rin lati ahin titi de iseyin Eni ma yini, a
yini Eni o
ni yini, ko ni yini Se bo'timo ore Se bo'timo ore mi Se bo'timo mama Se bo'timo baba mi