音效
界面
难度等级
口音
界面语言
1
和/或在社交方面支持我。网络:
Àkọ́kọ́
(专辑: 9: Ésan - 2021)
Emi ni emi leni na Okunrin meta at'abo to n
forin ko Emi ni emi lomo na Okunrin merin at'abo won tenu mo Mo lanu, mo soro Mo y'ake, mo fo ro Omo oloforo, mo j'akara oforo Emi ni ah, emi ni oh Emi ma leni to n
so nigboro Emi ni ya, emi ni yo Awon mama gan soro ni popo Won le mi l'akoko Won le mi l'akoko oh Won le mi l'akoko oh Won le mi l'akoko oh Emi ni, okunrin na T'awon majesi sope o'morin gan Emi ni, emi lomo na Gbogbo aradugbo lo n
tenu mo Emi baba olowo Mo sowo, mo jere Iwa at'opolo lo n
lo Awon ota ti rupo Emi ni ah, emi ni oh Emi ma leni to n
so nigboro Emi ni ya, emi ni yo Awon omoge redi ni popo Won le mi l'akoko (iwo l'akoko) Won le mi l'akoko oh (iwo l'akoko oh) Won le mi l'akoko oh (iwo l'akoko) Won le mi l'akoko oh (iwo l'akoko) Won le mi l'akoko (iwo l'akoko) Won le mi l'akoko oh (iwo l'akoko oh) Won le mi l'akoko oh (iwo l'akoko) Won le mi l'akoko oh (iwo l'akoko)
完毕